ETO ADIYELOFO

Written by on October 10, 2019

Ijoba Ipinle Eko ti kesi awon olugbe lati lo forukosile feto adiyelofo ilera NHIS, tijoba ipinle Eko gbekale fun ipese ilera to jiire.

Gomina Babajide Sanwo-Olu lo soro naa nibi apero eleekesan iree tawon alase Eto Ilera niwo oorun ile adulawo to waye ni Victoria Island.

O sope taraalu ba forukosile feto adiyelofo ilera naa lo maa ran ijoba lowo lati pese ilera to gbamuse fawon olugbe lowo ti ko ga jara lo.

Gomina Sanwo-Olu sope, amojuto ilera sepatake ko too gberegedie monilara pelu arowa sawon olugbe ilu eko lati mase fowo yepere mu itoju dera won tori alaafia la fi nlo ile aye

Ninu oro alakoso olusafihan ise opolo nibi apero naa, Ogbeni Ryan Sanderson lo tosope afihan ni won fee fi sawari ojuutu  sisoro ilera eda nile yi ati loke okun.

Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background