GOMINA BABAJIDE SANWO-OLU SO PE AABO SE PATAKI

Written by on October 10, 2019

Ijoba Ipinle Eko tun ti tenumo ilakaka re lati jeki eto aabo gbogbo dee nilu Eko.

Gomina Babajide Sanwo-Olu lo soro aridaju  naa nigba to gbalejo egbe Carveton Offshore support Group lalejo ni Mirina.

Gomina Sanwo-Olu tenumo pe ilu to ba toro ni owo sise to maa nroju, to si nfi okan awon onileese bale pe ilu Eko dara lati kowo sowo nbe.

Ninu oro alaga egbe naa, Ogbeni Aderemi Makanjuola to ba gomnina yo fun ipo tolorun gbewon de, naa gba gomina ni moran lati gunle isejoba akoyawo ki rora lo.

O seleri pe egbe naa yoo sowopo pelu ijoba ipinle Eko lati mase jeki ipese aabo mehe nilu Eko.

Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background