IJOBA IPINLE EKO KEDE LATI FOPINSI IWAKUWA AWON OLOKADA

Written by on January 14, 2020

IJOBA IPINLE EKO TI KEDE ETO LATI FOPINSI LILO OFIN IRINA WOLE LATIWO AWON OLOKADA ATAWON ONI KEKE ELESE META.

ATEGADE KOMISONA FETO IROYIN ATI OGBON ATINUDA, OGBENI GBENGA OMOTOSHO FIDIRE MULE PE ETO SISIDE AWON TO NTAPA SOFIN IGBOKEGBODO OKO TO NLO LOWO NILU EKO YOO TO KARI GBOGBO ILU EKO.

KOMISONA SALAYE PE, IWAKUWA AWON OLOKADA LOJEKI IJOBA BERE AMULO LOKOTUN OFIN IGBOKEGBODO OKO ODUN 2018, KI ALA ISEJO TO WA LODE LE WASI IRINSE NIPA JIJEKILU EKO DI GBEDEMUKE.

OGBENI OMOTOSHO SOPE IJAMBA OKADA TO NPOJU LOJEKI IJOBA IPINLE EKO GBE OFIN IRINNA ODUN 2012 JADE, EYI TI WON SATUNBO RE KEYIN  LODUN 2018.

 O SOPE ISELE IDIGUNJALE OGBON LO WAYE LATOWO AWON OLOKOADA LODUN 2019 TO SI JEKI OGUN LARA RE LAWON OLOPA GBINAYA LATI MASE JE KI WAYE RARA, TI WON SI FOWO SEKUN OFIN MU AFURASI MEEDOGBON EYI TI WON RI OUN IJA OLORO MEJIDINLAADOTA GBA LOWO WON.

OGBENI OMOTOSHO SOPE, IJOBA TO WA LODE KI  FEE FOWO YEPERE MU ETO AABO PAPAJULO IWAKUWA AWON OLOKADA.

Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background