- AARE MUHAMMADU BUHARI BUWOLU OFIN ETO
ISUNA OWO
- OWO AJO EFCC TE AWON OMO ONI JIBITI ORI
ERO ALELUJARA (YAHOO BOYS) MEJO NI ILU IBADAN
- IJOBA IPINLE KWARA BE AARE BUHARI WO
PELU IWE IPOUNGBE
- ILE EJO TO GA JULO SUN IDAJO GOMINA MEJE
SIWAJU
- META-DI-LAADOJE AWON OMO ORILE EDE
NIGERIA, GHANA ATI BEBELO NI WON TI YO
LOKO ERU NOBI SILE
- OJOGBON WOLE SOYINKA SOWIPE EBUN ODUN
TITUN NI ‘’AMOTEKUN’’ JE FUN WA
- AWON EGBE OLUKO NLE YI FE SE IPADE PELU
AARE LORI GBEDEKE OJO ORI TI WON O MAA FISE SILE
- ILE EJO DA EJO OWO IFEHINTI TI IGBAKEJI
GOMINA IPINLE TARABA TELE GBE TOO NU
- GOMINA SEYI MAKINDE TI ILU OYO NI OUN KO
NI WO ILE ONILE LAI NI AJOSO
Reader's opinions