WON PE AWON OLORI IJO LATI MAA WASU IGBALA OKAN

Written by on January 15, 2020

Won ti pe awon olori ijo olorun nija lati seto isoji maa jeki iberu olorun sodo sokan aya awon eeyan ileyi, mki alaafia le maa joba niso lagbo oselu ijoba tiwatiwa.

Alakoso ijo World Soul Winning evangelical Ministry, WOSEM, Pastor Paul Obadare ti soro ipenija  naa nibi apero pelawon oniroyin nibi afilole isoji Koseunti to maa waye loododun, niranti oludasile ijo WOSEM, oloogbe Prophet Timothy Obadare.

Pastor Obadare sope awon olori ijo olorun ni ojuse lati da ogo ileyi pada gege bo se wa laye ojoun ninu Eto Koseunti lasiko oloogba Obadare nibiti ife ti maa njoba.

Inu oro ojise Olorun Apostle Paul Adenuga lo ti sopejuwe iwa ajebanu to gbodekan gegebi abajade bawon ojiseolorun se dari iwasu ode iwoyi si wiwa oro dipo igbala okan.

O ro awon eni owo lati ran awon oloselu lowo ki won le fi adura maa tuko orile ede yi.

Pastor Paul Toluwani ti gbogbo enia mosi Baba lesekese romo Nigeria lati yago fawon ojise olorun to ti so raa won di igbakeji Olorun, dipo gbigbarale Olorun. Oniroyin wa Christiana Akano jabo pe isoji Koseunti je eto pataki ti Ologbe prophet Timothy Obadare se idasile re nigba aye won, ti se maa nmile pelu ise iyanu, Iwosan, Igbala, pipe fun ajoyo ayeye Isoji Koseunti beere ni ojo kokanlelogbon osuyi titi di Ojo kinni Osu keji, Odun 2020 nipinle Ondo.

Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background