AWON GOMINA GOMINA NI GUSUU ILA OORUN SEPADE NILU EKO LORI ETO ABO LEKUN ILE YORUBA
Written by Christiana Akano on February 14, 2020
Awon gomina gomina ni ile Yoruba tise alaye pe kun sepe awon se idasile eso alaabo iwo orun ti won tinse Amotekun bikinse lati daabobo ileto ati ekun ile Yoruba lo.
Alaga igbimo awon gomina to tunje gomina ipinle Ondo arakunrin Olurotimi Akeredolun losoroyi nilu eto nibi aparo awon oniroyin todale pataki eto abo ekun naa leyiti won se pelu oga oloopa Muhammed Adamu.
Ipade naa waye lati se alekun ogbon atinuda lori eto abo ibile leyi Gomina Babajide Sanwo-Olu gbelejo won laarin. Igbekeji Gomina Dr. Obafemi Hamzat, Gomina Ipinle Ogun, ipinle Oyo, Osun ati Ekiti pelu awon Igbakeji won.onoroyin wa jabo pe idasile eso alaabo amotekun naa tida awuyewuye sile lati osu kinni odun yi lori ewu eyi toronmo.