IJOBA IPINLE EKO PEFUN IGBIYANYU GIDI LATI DEKUN TITE ETO AWON OMODE IMOLE
Written by Christiana Akano on February 12, 2020
Ijoba Ipinle Eko tipefun alekun akintiyan lati wa opin si isomo toute eto awon ogowere loju mole nitori pe isoro toute eto awon ogomere naa mole tise akoba fun awujo wa.
Dr Ibijeko Sanwo-Olu toje aya gomina losoroyi nibi eto iwode ipolongo lati dekun isoro ati ijiya ton kojo awon ogowere eyiti lleese tounri omo awon odo ati idagbasoke amujo eni nipinle Eko.
Eyiti won gbekale lati la araalu loye pelu didide tako gbogbo isoro ati iya toleefojuhan si awon odo wa.
Dr Sawo-Olu ti akoko naamo awon obi ati alagsate lati inoputo itopin awon ogomure won, atimpe ijoba ipinle eko tifi ayesele lati gbo esun, iwa ibaje tole fe kon awon ogbo were pelu pfin tosegbe leyin won ogo were pelu ofin tosegbe leeyin won.
Nitori Commissioner fun idagbasoke odo ati awujo wa, Olusegun Dawudu se alaye pe, pataki iwode naa ni lati fi agbenle fun araalu lati gbamikundi akundanya ijoba lojuna awon ogowere pelu ilani loye pe ijoba ipinle eko ti gbe ofin eto awon ogowere kale.
Ogbeni Dawodu tundi ebi opo isoro naa le isowo ise ati osi, ton jeku won maa fi ogo were se ise labura ati itaja loju popo ati ifowosowopo erun ati fifi majesi loko.
Ewe, aya gomina ati aya Igbakeji Gomna Arabirin Oluremi Hamzat awon omoegbe aya awon lobaloga lenu ise oba, Akowe Ajo naa, Arabinrin Yewande Falugba ati awon osise Ileese naa.