IJOBA IPINLE EKO SOPE LOJORI IPESE OUN AMADERUN SILU TIJOBA GUNLE NI LATI FA OJU OLIEESE LATI ILEEOKEERE MORA

Written by on February 12, 2020

Ijoba Ipinle Eko sope gbogbo ilakaka won lori ipese oun amayederun silu ko se lori fifa oju awon onileese lati le okeere mora ki won wa dasilosiwaju oro aje ilu Eko.

Gomina Babajide sanwo-Olu lo soro naa nigbe to gbalejo Olootu Brampton lati ni Ontario, nile Canada, Iyeh Ogbeni  Patrick Brown, ni Alausa.

Ogbeni Sanwo-Olu sope ki leto ka maa kasi awon omo Nigeria to wa loke okun lati maa bo wale wa da ise sile, ti ki ba si ayika to rorun fokoowo nile funwon.

O sope itan ile Canada farape ti lu eko pelatenumo pe ile mejeeji ti goke agba labala oro aje lalaimoye Odun seyin leka iroyin owo sise atamulo tekinoloji ode idoyi.

Gomina fimoriri hansi olootu naa fun lile won se faayegba omo nigeria lati rowomu wa npefun ajosepo pelawon alase ile Canada labala ipese aabo, ounje, mo ero ati bebelo.

Olootu naa wa fesi sigomina pe ajosepo to danmoran yoo fesemule laarin ilu mejeeji.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background