KOKO INU IWE IROYIN FUN OJORU OJO KEJILA OSU KEJI ODUN EGBA-O-LE-OGUN OLOOTU: ABDUL-FATAI ABDUL-GAFAR
Written by Christiana Akano on February 12, 2020
- EGBE CAN RO IJOBA APAPO PE KIO GBA NIGERIA SILE LOWO ADANU
- GOMINA ANA INPINLE ZAMFARA YARI SOPE ESUN TI WON FI KAN OHUN KO LESE NLE
- GOMINA IPINLE OGUN DR ABIODUN SOFUN IJOBA APAPO PE AWON YIO LE AWON AYEDERU TON WA OKUSA KURO NI IPINLE OGUN
- FANI KAYODE BE BUHARI PE KI O JEKI KANU SIN AWON OBI RE LAYO ATI ALAAFIA
- GOMINA MAKINDE TIGBA EGBERUN MEJE OLUKO ATI EGBERUN META-OLE-OGORUN META TIO KUNSE OLUKO SI AWONILEEKEKO IPINLE OYO
- OMO NIGERIA NAA TIRIDAJU PE EGBE OSELU PDP LO DARAJULO–BARAJE LO SO BE
- ILEEFOWOPAMO CBN SOPE WON KO GBODO KO MILIKI OLOMI WO ILEEYI MO, YATOSI ILEESE MEFA KAN
- ILEEGBEMO ASOFIN NI ISORO KAN SO TI AWON OMO NIGERIA TOWANI OKE OKUN NI PA ETO IDIBO BUHARI LOSOBE
Tagged as #Court