KOKO INU IWE IROYIN FUN OJORU OJO KERIN-DI-LOGBON OSU KEJI EGBA-ODUN-O-LE-OGUN OLOOTU: TEMITOPE OYEFOLU

Written by on February 26, 2020

  • ILE EJO DA EWON ODUN MEJE FUN OLISA METUH ALUKORO PDP TELERI
  • IJOBA APAPO PE AWON AMUGBALEGBE OSINBAJO TI WON YO NISE PADA
  • GANDUJE, GOMINA KANO KO AWON ONIBARA KURO NI KANO
  • AJO TO NGBO EJO AWON ONI INA MONAMONA PA LASE KI WON PI ERO AKANA (METER) FUN GBOGBO ILE
  • OGA OLOOPA NI ILE YI WOGILE AJO SAR’S NI IPINLE OGUN
  • AJO SERAP LODI SI OFIN IMUNITY FUN AWON SENETO
  • AJO NECO YO AWON OSISE MOKANDILOGUN NISE
  • ILE IGBIMO ASOFIN AGBA NSE IWADI LORI OWO-RI TO PO
  • ILE IGBIMO ASOFIN IPINLE OSUN NGBERO ISEKU PANI FUN ESUN AJINI GBE
  • AJO EFCC TI MAMA BOKO HARAM MOLE

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background