- YOO PADA RE IJA LORI BIJOBA SE TE ENU
IBODE PA, EGBE MAN LO SO BE
- AWON AGBEBON PA OSISE OGA AGBA KAN NI
ASO ROCK, WON DANA SUN OKU RE
- LORI ORO AMOTEKUN, ENU TI KO LAARIN AWON
ASOFIN ILEEGBIMO AWON IPINLE TO WUNI GUUSU IWO ORUN
- AWON AJINIGBE NI KOGI TUN JI ARINRINAJO
,EJILA PAMO, WON NBEERE OGBON MILIONU NAIRA
- AWON OLOOPA FOWO SIKUN OFIN MU OBINRIN
TO TA OMODUN META NI EGBERUN LONA AADOTALELEGBETA
- EGBE AWAKO ERO NURTW SELERI LATI DA GOBE
SILE NIBUDO IWOKO ERO NI OYO
- IJOBA APAPO SOPE AWON TI GBARADI LATI
KOJU ISORO CORONA VIRUS
- AJO ELETA IDANWO WAEC YO ORUKO ILEEWE
METADINLOGUN KORO NIPINLE BENUE LATI MASE SEDANWO WON MO
- IPINLE GOMBE KO MILLIONU MEJILELOGUN
NAIRA KALE LATI DEKUN AISAN LASSA FEVER
- A KO GBODO FAAYEGBA AWON OMO EGBE
AFEMISOFO LATI PIN NAJIRIA YELEYELE, AARE BUHARI SORO.
Reader's opinions