EGBE AWAKO OKO AFAYAFA KOSI IJOBA APAPO LATI PASE KISE AKANSE OJUNA MAROSE APAPA-OSHODI TETE PARI

Written by on March 9, 2020

Egbe awako oko afayafa nile Nigeria ti rawo ebe si ijoba apapo lati pase fawon agba isese to nsise ojuko marose Oshodi-Apapa ati Tincan si Mile 2 ki idamu to won nkoba awon awako oko afayafa dinku jojo.

Alaga Ebge naa, Otunba Olaleye Thompsom soro ipenija aa ninu iforowero pelu awon oniroyin lEko.

Otunba Thompson sope tise atunse ojupopo naa ba tete pari, yoo mu edinku wahala tawon awako nla koja, yoo si tun jeki oro aje gbe peeli si.

O lo afani naa fi rawo ebe si awon to ni oko afayafa lati tele ofin irina tabi gbe oko sibi ti ko tona.

Otunba Thompson tun rojobe lati satunse awon opopona to bayje kaakeri onle ede yii

Otunba thompson gbosuba funjoba apapo lati si sunkere fakere oko ni apapa pelafikun pe Komisona Ileese oloopa Ogbeni Hakeen Odumosu Ku afomoniyase fun kiko awon olpa lati safomo omi ganfe kuro ni apapo.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background