ABADOFIN AJO TO N RISORO AWON IPINLE IWO-ORUN GUUSU ILEYI PEGEDE FUN KIKA ELEEKEJI NILEEGBIMO ASOJUSOFIN

Written by on February 27, 2020

Abadofin to maa risi Ajo to nsakoso awon Ipinle to wani Guusu iwo Orun ileera to se bee moribi nibi ipinle kika eleekeji, nileegbimo asojusofin ileewa.

Latari atileyin tabadofin naa rigba latowo agbenuso ileegbimo asoju, ogbeni Femi Gbajabiamila atawon asofin mokanlelogorin miin, lo jeki won fenuko latari abadofin naa sodo awon omo igbimo alabesekoli to nrisi eto idajo nileegbimo asojusofin fun agbeyewo.

Lara awon asofin to nsegbeleyin abadofin naa sope ile aje nipinle  Eko je tawon ipinle to wani guusu iwo oorun pelu igbagbo pe leyin idasile ajo naa, yoo modagbisoke ba ekun naa atiti Nigeria lapapo.

Abadofin naa laa kedere pe oluleese ajo naa yio wanilu Ibadan, ipinle Oyo pelu kiko Eka ofiisi sawon ipinle to ku bii ipinle Eko, Osun , Ondo, Ekiti ati Ondo.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background