AMORAN TI LO SODO AWON OMO NIGERIA LATI RIRA WON GEGEBI OKAN

Written by on November 12, 2019

Won ti kesi awon omo nigeria lati samulo awon ohun to rewa ninu bOlorun se da wa papo gege bi Orile –ede.

Ojogbon Stephen Banji-Akintoye , asofin laakoko iselu eleekeji lo soro amoran yin pelu Oniroyin wa Christiana Akano nIkeja.

Asofin Banji-Akantoye ko sai gba awon omo nigeria nimoran lati jinna si awon aleebu to wa ninu iwa olaju atohunrin wa nipa a n gbagbe asa ati se wa.

O so pe, ko to di akoko ti awon oyinbo mu ile yin sin, la a ti ni orisinrisi eya pelu eto isejoba onikaluku won.

Senator Banji-akintoye wa rawo ebe seka ijoba meteeta lati gbe awon eto ti yoo ro awon araalu lorun kale pataki julo leka eto oro aje ati oselu.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background