Author: Christiana Akano

Page: 2

Pelu bawon Kristen lagbaye se asajoyo ayajo Ojoru Eeru lori ode yin, won ti fun omo Nigeria papajulo awon kristen nimoran lati sunmo Olorun ninu adura , ise ore ati emi arojinle.

ILE EJO DA EWON ODUN MEJE FUN OLISA METUH ALUKORO PDP TELERI
IJOBA APAPO PE AWON AMUGBALEGBE OSINBAJO TI WON YO NISE PADA

IKOLU-KOGBA NIPINLLE BAYELSA NI GBATI SUPREME COURT NI APARO FUN DEBENI DAVID-LYDN NINU EGBA APC PEDUN OGBODO EGBE ASEFUN

Aya Gomina ti Ipinle Eko, Dokita Ibijoke Sanwo-Olu ti se ileri lati tesiwaju ati maa se iranlowo fun awon alaini ni Ipinle Eko papajulo, awon ti ijamba ina sele si ni Agbegbe Abule-Egba ni ibere Osu kinni Odun yi ti won si ko won lo si LASEMA IDO Camp, ni Igando.

YOO PADA RE IJA LORI BIJOBA SE TE ENU IBODE PA, EGBE MAN LO SO BE
AWON AGBEBON PA OSISE OGA AGBA KAN NI ASO ROCK, WON DANA SUN OKU RE

´╗┐Awon gomina gomina ni ile Yoruba tise alaye pe kun sepe awon se idasile eso alaabo iwo orun ti won tinse amotekun bikinse lati daabobo ileto ati ekun ile Yoruba lo.

IKOLU-KOGBA NIPINLLE BAYELSA NI GBATI SUPREME COURT NI APARO FUN DEBENI DAVID-LYDN NINU EGBA APC PEDUN OGBODO EGBE ASEFUN

Ijoba Ipinle Eko tipefun alekun akintiyan lati wa opin si isomo toute eto awon ogowere loju mole nitori pe isoro toute eto awon ogomere naa mole tise akoba fun awujo wa.

Ijoba Ipinle Eko sope gbogbo ilakaka won lori ipese oun amayederun silu ko se lori fifa oju awon onileese lati le okeere mora ki won wa dasilosiwaju oro aje ilu Eko.

EGBE CAN RO IJOBA APAPO PE KIO GBA NIGERIA SILE LOWO ADANU


Current track

Title

Artist

Background