Author: Christiana Akano

Page: 4

GOMINA IPINLE EKO BABAJIDE SANWO-OLU TIRONSE IBANIKEDUN SI AWON TI IJAMBA INA SE LOSE NLU ABULE EGBA

ILE EJO TO GA JULO BUWOLU IDIBO SIPO GOMINA GANDUJE, LALONG, TAMBUWA ATI MOHAMMED
OLU ILE-ISE OLOGUN ILEYI RO AJO ORILE EDE ILU OYINBO LATI FOPIN SI ATILEHIN AWON EESIN O KOKU

AWON AGBAAGBA ILE YORUBA ATI AWON AGBEJORO AGBA BU ENU ATE LU MALAMI LORI OHUN TI O SO NIPA AMOTEKUN

Won ti pe awon olori ijo olorun nija lati seto isoji maa jeki iberu olorun sodo sokan aya awon eeyan ileyi, mki alaafia le maa joba niso lagbo oselu ijoba tiwatiwa.

ISEJOBA TOWA LODE NIPINLE EKO YIO TUBO TESIWAJU IGBESE IMOTOTO AYIKA NIPASE AJOSEPO TO DANMORAN PELAWON, PAAJULO AWON OBINRIN ATAWON ONTAJA.

ILEEGBIMO ASOJUSOFIN TI PAA LASE PE KO GBODO WAYE O, IYEN BI AJO TO NRISI IDIYELE OWO INA MONAMONA SE NGBORO LATI SALEKUN IYE OWO INA TARAALU NLO.

AWON ESO KANPA-TASK FORCE TI PRESIDENT OFFICE LABE IGBAKEJI ALAGA KAYODE OPE-IFA TI KE GBAJARI SITA LORI AWON TIO NI DUKIA LEGBE OMI FI YI AGBEGBE WON SI BI AWON OKO AFAYAFA PELU GORODOMU LORI N GBE AWON OKO WON SI

E pade Oniroyin wa, Ade Adegbola kete ti agogo mewa aro balu fun #Iroyiniyaleta #BondFM929. E maa bawa bo.

Adupe lowo gbogbo eyin ololufe wa fun adurotiyin bee see n tetisiwa. #BondFm929, ore araalu laje.

IJOBA IPINLE EKO TI KEDE ETO LATI FOPINSI LILO OFIN IRINA WOLE LATIWO AWON OLOKADA ATAWON ONI KEKE ELESE META.


Current track

Title

Artist

Background