Author: Christiana Akano
Page: 5

AARE MUHAMMADU BUHARI BUWOLU OFIN ETO ISUNA OWO
OWO AJO EFCC TE AWON OMO ONI JIBITI ORI ERO ALELUJARA (YAHOO BOYS) MEJO NI ILU IBADAN
IJOBA IPINLE KWARA BE AARE BUHARI WO PELU IWE IPOUNGBE
Ijoba ipinle Eko lerileka lati le gbogbo awon alase ile faaji alaale jakejado ile Eko pa, eyikeyi tejo re ba ti kanjola lara pe a ti pe, ayaafi ti araalu lowo, njoba a ti pe, ayaafi tegbe idagbasoke agbegbe naa ba fowosi ki won bere ise pada.

Ileejo kotemilorun to fikale silu Ilorin ti jawe gbele e fun omoileegbimo asofin ipinle Kwara, to nsoju ekun Guusu Ilori labe asia egbe All Progressive Congress, APC Ogbeni Abdul Azeez Oluwawulo, ti won si kede omo egbe oselu Peoples Democratic party, PDP, Ogbeni AbdulRaheem Agboola jejebi eni to jawe olubori lati eyi ekiro naa.
Aya gomina Ipinle Eko, Arabirin Ibijoke Sanwo-Olu ti so si gbogbo eniyan leti pe, oun ko ni nkankan se pelu eto egbe ti ki i se tijoba kan South-Westtuie Health Trust lati maa ko awon to ku die kaato fun kuro loju popo.
Ijoba ipinle Eko ti fi ifokansi re han pe, eto akanse ile egbe Ilubinrin yoo pari lodun 2020.
Won ti kesi awon omo nigeria lati samulo awon ohun to rewa ninu bOlorun se da wa papo gege bi Orile –ede.
Omo Nigeria ni ojuse lati sowopo pelawon oloselu wa lojuna ati lulo mayederun faraalu.

Won ti kesi awon alase ileese panapana ijoba apapo atawon osise ajo to ndahun lasiko isele pajawiri lati tubo kojumose won lati dekun ijamba to nwaye lemolemo lawon oja wa lasiko.

Ijoba Ipinle Eko fi okan awon akeko ileewe ijoba ipinle Eko bale pe aabo gidi wa fun emi ati dukia won.

ILEEJO KAN LORILE EDE GBANA JU OMO NAIJIRIA SI EWON LORI ESU IBALOPO PELU OMODE
AWON OLOJA KAWO LORI LATARI OJA BALOGUN TO JONA