Author: Christiana Akano
Page: 6
GOMINA BABAJIDE SANWO-OLU TIPINLE EKO tisope oro to nlo lowo pelawon alase Ileese apinnaka agbegbe Niger Delta lati maa pese ina monamona fun ipinle eko, fun igbadun ijoba tiwantiwa.
Ajo eso asobode ti sope atejade kan to gbana eburu bo sode, eyi to sopin ofin lati enuubode ile yio wa sopin lojo kokan lelogun osu kinni odun 2020, kiise otito botiimu o mo.
E YI GOMINA TI KO BA LE SANWO OSU TO KEREJULO FAWON OSISE KURO NIPO, EGBE OSISE NLC LO SO BE
AWON AFURA MEJI RA OMO MEJI NI EGBERUN LONA OGOJE NAIRA
ILAJI OWO AGBE YIO MAA FI RA IRINSE WON, MINISITA LO KEDE ORO
GOMINA ANA NIPINLE EKO AMBODE GBE ILEGBIMO ASOFIN LOSI ILEEJO.
OPIN IRIN AJO DE FUN ATIKU LORI IDIBO TOGBE BUHARI WOLE.
SECONDUS SOPE EGBE OSELU PDP TIFI IJASILE FUN OLORUN JA LEYIN IDAJO ILEEJO SUPREME COURT.
Ileegbimo asofin Ipinle Eko ti buwolu atunto akosile Eto Isuna Odun 2019 gegebi gomina Babajide Sanwo-Olu se nbeere fun.
Ijoba Ipinle Eko loun ko ni feti layti seto ayika ti yoo faye gba awon odo lati samulo ebun won fun agbega Ipinle yii. Alamojuto fun awon odo ti idagbasoke amuludun, Ogbeni Segun Dawodu lo soro yii nibi iside eto IBILE to waye ni Onikan youth Centre ni Lagos Island. Ogbeni Dawodu […]
Aare Muhamadu Buhari ti kilo fawon olopaa lati sora se nipa lilo ipa ati agbara lona aito fawon odo latari oro aigbogun ti iwa madaru ayelujara.
Ijoba ipinle Eko ti se ifilole Igbimo awon odo Ile yii eka ti Eko. Alamojuto fun odo Ogbeni Segun Dawudu to ohun Nikeja ro awon ika asiwaju lati fi awon odo sokan ki won si ri i idaju pe, alafi joba laarin won nile yii.
AWON AYEDAADE OSISE NLC TIFAGILE IYONSELODI WON WIPE ORO SIN TESIWAJU.
IJOBA APAPO TO SOPE KO SOTO NINU FIDIO TAWON KOLORANSI EDA KAN LO GBE SORI ERO ALATAGBA PE WON KOLU OFUSI AWON ASOJU ILE NIGERIA TO WANI COTONU, LORILE EDE BENIN REPUBLIC.