AWON PANAPANA ATAWON OSISE PAJAWIRI NJA FATAFATA LATI PA INA TO NJO LOJA BALOGUN, PELU BI GOMINA SANWO-OLU SE LOSIBASWLW NAA

Written by on November 6, 2019

Won ti kesi awon alase ileese panapana ijoba apapo atawon osise ajo to ndahun lasiko isele pajawiri lati tubo kojumose won lati dekun ijamba to nwaye lemolemo lawon oja wa lasiko.

Alukoro Egbe oselu Action Democratic Party, ADP, omoba Adelaja Adeoye lo soro ipenija naa ninu atejade to si sile ninu Abuja, pelu ijamba isele ina jijo to waye loja Balogun lati bamgbose losi Broad street.

O kesi ijoba apapo lati tubo pase fawon osise panapana kise won le tubo darasi pelu bo se kedun pelawon to padanu emi won ninu ijamba ina naa.

Omooba Adeoye wa rojoba ipinle Eko lati seto itoju ojidi fawon to lugbadi irufe isele bee.  


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background