News

#Loripapa ni #Eto ten gbo lowo lori afefe latenu AbdulFatai ati Bobo Karo. E maa yin kuro nibe

Awon #Eto, #Iroyin ati #Ipolowooja ni Ede Yoruba n tee siwaju titi di agogo mejila-abo osan #Bondfm929. E maa bawabo

Egbe awako oko afayafa nile Nigeria ti rawo ebe si ijoba apapo lati pase fawon agba isese to nsise ojuko marose Oshodi-Apapa ati Tincan si Mile 2 ki idamu to won nkoba awon awako oko afayafa dinku jojo.

Ijoba ipinle Eko ti rawo ebe sawon ero ti nlo ojuupopo lati se suru fun ijoba toripe won o feki ojo sakoba fawon ise akanse lo jeki won dawole opolopo ise akanse papo lasiko kan naa.

EGBE ASUU ATAWON MIRAN FAJURO SI SISUN AYEYE ASEKAGBA AWON AKEKO UNILAG SIWAJU
OKO AFAYAFA SEKUPA MOLEBI ELENI MARUN LORI OKADA NI KANO

Awon agbebon pa Eeyan meji, won ti ji alufa ijo Aguda gbe ni Kano,Benue .
Eni meji ti won furasi nipa Corona virus nilu Eko yege leyin ayewo ilera won, ko si aisan naa lara won.
Ileegbimo asoju beerefun alekun ipese owo fun amojuto corona virus .

Gomina Ipinle Eko, Ogbemi Babajide Sanwo=Olu ti fajuro sowon gogo ti won nta omi ifowo aoakokoro ati ibomu latari bi ero se nro ketiketi lo ra loja nitori aisan coronavirus to seleru nilu Eko latowo omo Italy to ko aisan naa wa silu Eko, ti won si fo sahamo sisamojuto ilera re leaye oto.

´╗┐Abadofin to maa risi Ajo to nsakoso awon Ipinle to wani Guusu iwo Orun ileera to se bee moribi nibi ipinle kika eleekeji, nileegbimo asojusofin ileewa.

Ijoba Ipinle Eko sope, omo Ile China ti won mulo sileewosan Reddinghton nilu Ikeja latari pe won furasi pe o ni aisan Corona Virus , ni iwadi awon onisegun oyinbo pada fidere mule pe saka lara re da o.


Current track

Title

Artist

Background