News

Page: 3

AWON AGBAAGBA LOKE OYA SOPE AARE BUHARI KO KUNJU OSUNWON TO LATI GBE NIGERIA DE ILE ILERI
ORO TI DARU MO AWON GOMINA NI OKE OYA LOWO O LORI OFIN IDASILE OPERATION SHEGE KAFASA

Gbigbe agbara fun awon odo ni akori dida be fun omo obinrin tOdun yin (International Day of Zero Tolerance for Female Genital Mutilation, 6 Feb 2020 Theme: Unleashing Youth Power)

Awon obinrin ti won ba dabe fun maa koju isoro bi eru biba, inira, eje dida, arun, inira lati too pelu awon inira nibi ibalopo, aisan opolo ati eto ilera won.

Ijoba ipinle Eko ti fidi okodoro oro mule pe awon tii fenuko lori oro awoon olokada ero atawon onikeke elese meta, Marwa lori opopona ti won ko gbodo gba nilu Eko.

Adele Ogaagba ajo to ndekun iwa ajebanu EFCC, Ogbeni Ibrahim Magu sope ko dinsi mejidinlogun lara awon ti won kowo ilu yi sapo araawon ti won yoo fi tipa tikuuku wo lati wa jeje laipe.

Ijoba Ipinle Eko sope awon fee fowosowopo pelawon alase ileese elepo ileewa NNPC, lori ilana amojuto awon opa epo to gba ilu Eko koja .

E pade oniroyin wa Ade Agbola kete ti agogo mewa baalu fun #IroyinIyalete #Bondfm929. E maa bawa bo

OWO ELE ORI EPO TIJOBA APAPO NFUN AWON OLOJA EPO SEESE KO TUN LO SOKE LATARI ALEKUN TI WON NBEERE FUN

OPO AWON AKOROYIN SIN SELEDE LEYIN OGA AGBA ILEESE RADIO IJOBA APAPO TELERI OMOBA ATILADE ATOYEBI TOSEWALE ASA

AARE BUHARI SOPE TITI IBODE ILEEYI TI KOJA ORO DARUKE OUJIJE NIKAN


Current track

Title

Artist

Background