Politics

Page: 3

Ijoba Ipinle Eko sope awon fee fowosowopo pelawon alase ileese elepo ileewa NNPC, lori ilana amojuto awon opa epo to gba ilu Eko koja .

OWO ELE ORI EPO TIJOBA APAPO NFUN AWON OLOJA EPO SEESE KO TUN LO SOKE LATARI ALEKUN TI WON NBEERE FUN

OPO AWON AKOROYIN SIN SELEDE LEYIN OGA AGBA ILEESE RADIO IJOBA APAPO TELERI OMOBA ATILADE ATOYEBI TOSEWALE ASA

AARE BUHARI SOPE TITI IBODE ILEEYI TI KOJA ORO DARUKE OUJIJE NIKAN

GOMINA IPINLE EKO BABAJIDE SANWO-OLU TIRONSE IBANIKEDUN SI AWON TI IJAMBA INA SE LOSE NLU ABULE EGBA

ILE EJO TO GA JULO BUWOLU IDIBO SIPO GOMINA GANDUJE, LALONG, TAMBUWA ATI MOHAMMED
OLU ILE-ISE OLOGUN ILEYI RO AJO ORILE EDE ILU OYINBO LATI FOPIN SI ATILEHIN AWON EESIN O KOKU

AWON AGBAAGBA ILE YORUBA ATI AWON AGBEJORO AGBA BU ENU ATE LU MALAMI LORI OHUN TI O SO NIPA AMOTEKUN

Won ti pe awon olori ijo olorun nija lati seto isoji maa jeki iberu olorun sodo sokan aya awon eeyan ileyi, mki alaafia le maa joba niso lagbo oselu ijoba tiwatiwa.

ISEJOBA TOWA LODE NIPINLE EKO YIO TUBO TESIWAJU IGBESE IMOTOTO AYIKA NIPASE AJOSEPO TO DANMORAN PELAWON, PAAJULO AWON OBINRIN ATAWON ONTAJA.

ILEEGBIMO ASOJUSOFIN TI PAA LASE PE KO GBODO WAYE O, IYEN BI AJO TO NRISI IDIYELE OWO INA MONAMONA SE NGBORO LATI SALEKUN IYE OWO INA TARAALU NLO.


Current track

Title

Artist

Background