Sports

#Loripapa ni #Eto ten gbo lowo lori afefe latenu AbdulFatai ati Bobo Karo. E maa yin kuro nibe

OONI ILE-IFE OBA ADEYEYE OGUNWUSI SE IPADE PELU AARE BUHARI LORI ONA ABAYO BI O SE NI SI OGUN NILEEYI.
AWON OJELU OLE TON JA IJOBA LOLE NILE ADULAWO LOFA ISORO ETO ABO BUHARI LOSOBE.

IWADI FIHAN PE AWON ASOFIN ILEEYI, AWON OLOPA ATI AWON ADAJO NI OLORI AWON OJELU NILEEYI.
AWON MEKUNNU ILEYI TIGBERA LATI MERINDIN LAADORIN MILLIONU SI MEJIDINLOGORUN MILLIONU LAARIN ODUN MEWA.


Current track

Title

Artist

Background