ETO EKO ATI IRONI LAGBARA

Written by on October 10, 2019

AGBARA ETO IDAGBASOKE NI GBOGBO AGBEGBE KO SE LEYIN ETO EKO TI A BA FUN AWON AKEKOO LATI IPELE ILEEWE ALAKOBERE.

AKOWE AGBA IJOBA IBILE OSHODI-ISOLO, OGBENI ABIOLA OLADIPO LO SORO YII NIBI ETO NILAGBARA FUN AWON OGO ATI PINPIN  IWE ATAWON OHUN ELO MIRAN FUN AWON AKEKO NI ILEEWE ALAKOBERE MERI

N OTOOTO NIJOBA IBILE OHUN.

OGBENI OLADIPO SALAYE PE, PATAKI EKO GBODO JE GBINGBIN SOKAN AWON AKEKOO NILEEWE ALAKOBERE GEGE BI TI GBA NI ATI LATI LE JE KI EKO KIKO WU WON.

OLUGBAETO OHUN KALE , KAN SILO TO MN SOJU EKUN IROODU KEJI NI SHOGUNLE, OGBENI MUSTAPHA WASIU SO PE, O SE PATAKI FUN AWON ASOFIN LATI MAA NAWO AANU PADA SINU AWUJO PELU AFIKUN PE IGBE-AYE AWON OPO TI PE E MEHERE PUPO LEYI TI AWON GBODO JO GBARUKU TI.

ONIROYIN WA CHRISTIANA AKANO JABO PE EGBE AWON EEKAN ILU LO WA NIBE LA A TI RI, ASAAJU EGBE OSELU APC, LOSHODI-ISOLO, OGBENI RASHEED OBASA, AWON SOFIN, ONISE-OWO, AWON OBI, OBA-ALAYE, AKEKOO TI WON SI PIN ORISIRISI EBUN FUN WON.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background