Gbogbo awon toro kan kede ki opin deba dida be fobinrin

Written by on February 6, 2020

Awon obinrin ti won ba dabe fun maa koju isoro bi eru biba, inira, eje dida, arun, inira lati too pelu awon inira nibi ibalopo, aisan opolo ati eto ilera won.

Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background