GOMINA IPINLE EKO BABAJIDE SANWO-OLU TI RANSE IBANIKEDUN SI AWON TI IJAMBA INA SE LOSE NI ABULE EGBA, NI EKO

Written by on January 21, 2020

GOMINA IPINLE EKO OGBENI BABAJIDE SANWO-OLU TIRONSE IBANIKEDUN SI AWON TOPADANU MELEBIWON ATI DUKIYA WON NIBI IJAMBA INA TOSELE NI AGBEGBE ABULE EGBA LOJO SUNDAY.

OGBENI SANWO-OLU SOROYI GEGEBI ATEJADE TI OGBENI GBOYEGA AKOSHILA FISITA NIIPE GOMINA SOPE ISELE NAABA OKAN JE EYI TOOSE LORI AWON TON DI ONA EGBERU WA OWO TOSIJE AKOBA FUN OMO-AJE.

GOMINA SANWO-OLU KESI AWON ESO ALAABO LATI SA IPA WON KI WON SI FI OJU AWON ONISE LAABI NAA HAN PELU IJIYA TO GBOPON LOJUNA ATI WA OJUTUSI ISORO NAA LAWUJO ENI.

GOMNINA EKO KOSALAI RO AWON ODO LATI JUNA SI AWON IWA ODARAN BI FITO OPA EPO, ATIBEBELO DIPO EYI KI WON MAA LO OGBON, OYE ATI AGBARA WON FUN IDAGBASOKE AWUJO WA.

OGBENI SANWO-OLU SITUN KI AWON OSISE PARAPA ATI AJO ISELE PAJAWIRI KI ISE TAKUNTAKUN PELU ALAYE PE IJOBA TIGBA ABO IWADI IJAMBA INA NAA, LATI GBEGBESE LORIRE.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background