Gomina Ipinle Eko fi aidunu hansi alekun to deba iye ti won nti omi ifowo apakokoro-Sanitizer, ibowo atawon eoja miin latari pe coronavirus wolu Eko
Written by Christiana Akano on March 2, 2020
Gomina Ipinle Eko, Ogbemi Babajide Sanwo-Olu ti fajuro sowon gogo ti won nta omi ifowo aoakokoro ati ibomu latari bi ero se nro ketiketi lo ra loja nitori aisan coronavirus to seleru nilu Eko latowo omo Italy to ko aisan naa wa silu Eko, ti won si fo sahamo sisamojuto ilera re leaye oto.
Gomina so fawon akoroyin pe inu oun ko dun lasiko to lo sebewo sileewosan tomo Italy naa wa ni Mainland Hospital to wani Yaba, pelafikun pe ko bojumu bomo Nigeria se lo anfani oun to wa nigboro fi maa pawo ojiji

Gomina Sanwo-Olu so aridayu oro pe laipe ibese nbo latowo awon alase lori ipolongo didekun atankale aisan naa.
Saaju ni komisona Eto Idera, Ojogbon Akin Abayomi ti sope ayewo fihanpe ilera omo Italy to ngbaloju naa n ilosingin, o salaye pe aaye oto naa le gba alaisan ogonrun laisi idiwo nilara itewogba lagbaye\
