GOMINA IPINLE EKO KEDE ILU O FARARO LATARI AWON OPOLOPO OJUPOPO TO TI BAJE KOJA AALA NILU EKO
Written by Christiana Akano on October 14, 2019
IJOBA IPINLE EKO TI KEDE ILU O FARARO LORI AWON IPO TANWO OJUNA GBOGBO WA JAKEJADO ILU EKO.
GOMINA BABAJIDE SANWO-OLU TI WA PAA LASE KISE BERE A PEREN LANWO OJUUPO LATONI ODEYI, LEYIN PADE PELAWON AKOSEMOSE AMOJI ERO LATILEESE MEJO OLOOLO
NINU ATEJADE AKOWE IJOBE, OGBENI GBOYEGA AKOSLILE NI GOMINA SANWO-OLU TI SALAYE PE AWOM NIMOLARA OHUN YARALU EKO IILA KOJA LOJUUPUPO LATARI AWON OJU ONA TO TI BOYE
O SOPE GIGUNLE ISE ATUNSE OJUUPUPO NIKAN LONA ABAYO
GOMINA SOPE ISE ATUNSE OJUUPUPO MERINDINLOGOFA NI YOO BERE NI PEREU LAFIKUN ISE ATUNSE TO TO NLO LOWO LAWON OJUNA NLA-NLA TO LENIGBA
O WA RAWO EBA SAWON OLUGBE LATI SE SUURU PELU IJABA LAWON ASIKO TISE ATUNSE AKA YOO FI WAYE