IJOBA APAPO SOPE PANPE OBA YIO MU AWON OBAYEJE TI OHUN BA AMAAYEDEUN IJOBA JE

Written by on August 26, 2019

Ijoba apapo sope awon yio gbena woju enikeni tobada Ise Amayederun tijoba pase saarin ilu.

Oludamoran pataki si Aare Buhari lori oro Amojuto oun amayederun, Arabirin Maryam Uwais losoro ifanileti yi nilu Abuja.

Arabirin Uwais se afikun pe ijoba apapo yio tesiwaju pelu ofin ati alakaale, laise magomago isejoba Aare Muhammadu Buhari.

Arabirinn Uwaise se atenumo pe Ajosepo nsise pelu awon eso alaabo lati gbena woju awonti owo batiba pe ouba dukunja ijoba atawon ohun amayederun je pelu fifi ojuba ile ejo.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background