IJOBA IPINLE EKO FOFINDE AWON ILE FAAJI ALAALE ATAWON TO N FAARIWO DI ALADUGBO LOWO

Written by on November 13, 2019

Ijoba ipinle Eko lerileka lati le gbogbo awon alase ile faaji alaale jakejado ile Eko pa, eyikeyi tejo re ba ti kanjola lara pe a ti pe, ayaafi ti araalu lowo, njoba a ti pe, ayaafi tegbe idagbasoke agbegbe naa ba fowosi ki won bere ise pada.

Komisona Eto Ayika Ogbeni Tunji Bello ti pase fajo eleto ayika LASEPA lati fase ase naa muse dandan.

Ogbeni Bello sope eyi pa  dandan lateri opolopo ifisun latowo egbe idagbasoke ilu Eda to ti kanudara.

O woye pe opo ileetura atilejosin tijoba ti pada latatehinwa lo tun pada si fifi ariwo di araalu lowo ni.

Ogbeni Bello ro won toro kan lati maa ko ile lona tariwo kofi nii di aladugbo lowo tabi sakoba funilera araalu.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background