IJOBA IPINLE EKO RAWO EBE SAWON OLUGBE LATI SE SUURU FAWON ALASE LORI ISE AKANSE OJUPOPO JAKEJADO ILU EKO

Written by on March 9, 2020

Ijoba ipinle Eko ti rawo ebe sawon ero ti nlo ojuupopo lati se suru fun ijoba toripe won o feki ojo sakoba fawon ise akanse lo jeki won dawole opolopo ise akanse papo lasiko kan naa.

Oludamoran si gomina lori ise akanse amoju ero Aramide  Adeyoye lo soro na lasiko to sabewo awon ise akanse to nlo lowo lEko.

Ijoba Ipinle Eko fimoriri han sawon olugbe lati farada inira to romo bise akanse se nla lowo latari pe o sokinfa sukere lawon agbegbe kan.

Arabirin Adeyoye sope ipo tawon ojura wa lasiko ti sejonba to na lode bere ti baye ju lo jekijoba gunle opo ise atunse popo lati sedinku inira pelu riro araalu lati sowopo pelawon alaase na ki oun gbogbo le lo leto leto.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background