IJOBA IPINLE EKO TENUMO ILAKAKA RE LATI JEKI ILU EKO MAA WA NI MIMO TONITONI

Written by on January 15, 2020

ISEJOBA TOWA LODE NIPINLE EKO YIO TUBO TESIWAJU IGBESE IMOTOTO AYIKA NIPASE AJOSEPO TO DANMORAN PELAWON, PAAJULO AWON OBINRIN ATAWON ONTAJA.

AYA GOMINA IPINLE EKO, DR. IBIJOKE SANWO-OLU LO SATENUMO ORO PE EGBE AWON IYAWO OSISE IJOBA IPINLE EKO YOO TESIWAJU IFOWOSOWOPO PELAWON OLOJA LORI IMOTOTO OJA TO MAA NWAYE NIGBOGBO OJOBO FOSU MEFA GBAKO SASIKEJI.

DR. SANWO-OLU SORO NAA FAWON ONIROYIN NIBI IDANILEKO OLOJO KAN TO DALORI IMOTOTO OJA TI AABO LAOWN OJA WA BAYI TI EGBE AWON IYAWO OSISE IJOBA IPINLE EKO, COWLSO PELUIFOWOSOWOPO AJO TO NRISORO IJOBA IBILE NIPINLE EKO SAGBETENRUE, TO WAYE NI ALAUSA, IKEJA.

DR. SANWO-OLU TO JE ALAGA EGBE NAA SOPE O SEPATAKI LATI SETO IDANILEKO FAWON OLUGBE EKO LORI ONA TO BOJUMULATI SATILEYIN LATARI IPA TO NRI LORI AWUJO.

AYA GOMINA TENUMO PE, PE GBIGBE IDOTO SIBI TO YEE YOV RAN JOA LORI ETO SISI IDOTO DORO PELU IPESE ISE FARAALU.

DR. SANWO-OLU SALAYE PE LAYORI IPADE ISE DOTO TO BA TAGBAYE MII.

NINU ORO KOMISONA FORO IJOBA IBILE ATORO ISAGBASOKE ILU, ARABINRIN TETUNDE AROBIEKE LO TO KESI AWON IYALOJA ATI BABALAJE LATI TIGBIYANJU ISEJOBA GOMINA SANWO-OLU LEYIN IPESE AYIKA TO MO TONITONI ATI DIDEKUN GBIGBE OJA SEBA ONA ATAWON ORI-O-RU, ENI O JE TO NTASE OPERE SOFIN.

AWON IYALOJA BABALAJE LATIJOBA ISALE METADINLOGOTA NIPINLE EKO, ASOJU LEKA ETO AABO ATAWON LOOKOLOOKO LO PEJUPESE SIBI ETO NAA.

Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background