KOKO INU IWE IROYIN FUN OJO AJE OJO KERINLA OSU KEWA EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU: KEHINDE JIMOH

Written by on October 14, 2019

• AWON GOMINA ARIWA ATAGBAGBA FE PARI IJA JUKUN ATI TIV.
• E DEKUN A N BEERE OWO LOWO IJOBA EYIN OSISE E BEERE ISE TI WON -MAKARFI
• TI 0RILE-EDE NIGERIA KO BA GBA ATUNBI KO TO DI 2023 BOYA NI YOO JE ORILE – EDE MO – ATTAH.
• IDI TI MO FI LO FUN OSU MEJI-AISHA BUHARI.
• PDP ATI APC TUN FE GBE PEREGI KANA.
• OKOOLELOGORUN DIN KAN OMO NIGERIA NI WON N DURO DE IKU NI MALAYSIA.
• FAYEMI RO AWON OSISE LATI MASE YAN ISELODI
• ONISIRO –OWO AGBA NI NASARAWA PE FUN ADINKU OWONA IJOBA .
• E JE KA SORA SE FUN IROYIN AYEDERU –AISHA
• IJOBA APAPO NI LATI DASI ISORO OMIYALE NI KWARA.
• ATUNTO ILE YI NI ONA KAN TI ILE YI FI LE GOKE-AFRENIFERE
• EGBERUN MEJI OJISE OLORUN YOO GBADURA FUN NIGERIA NI BENIN.

Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background