KOKO INU IWE IROYIN FUN OJO ETI, OJOKONKANDINLOGUN OSU KEJE EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU: ABDUL-FATAI ABDUL-GAFAR

Written by on July 19, 2019

 • OONI ILE-IFE OBA ADEYEYE OGUNWUSI SE IPADE PELU AARE BUHARI LORI ONA ABAYO BI O SE NI SI OGUN NILEEYI.
 • AWON OJELU OLE TON JA IJOBA LOLE NILE ADULAWO LOFA ISORO ETO ABO BUHARI LOSOBE.
 • KALU SOPE, ENIYAN BI NELSON MANDELA NI ANIILO GEGE BI ASHIWAJU NILE ADULAWO.
 • AWON AGBAGBA LOKE OYA SOFUN AARE BUHARI PE YIO JE EBI TI WON BAKOLU AWON FULANI DARAN DARAN.
 • AWUYEWUYE GBALUKAN LORI ORO OWO OSU TOKEREJULO FUN AWON OSISE IPELE AKOKO DEPELE KEFA NIKAN.
 • ALAGA INEC KOJALE LATI YOJU SI ILEEJO TRIBUNAL LORI EJO BUHARI ATI ATIKU.
 • GHANA FI OMO NIGERIA OGORUN KAN ODIN MARUN SOKO PADA WASILE LAARIN OSU MEJIDINLOGUN.
 • BUHARI KII IMAM ABDULLAHI TI ILE AMERIKA FUN NI AMI EYE LOGO ENU.
 • FASHOLA SOFUN SANWO OLU PE KI O MAA PARI AWON ISE AKANSE ILU PAPAJULO ISE OJU IRIN RELUWE.
 • IHEDIOHA SOPE GBESE OWO BILLIONU OGORUN NAIRA NI IPINLE IMO JE.
 • IPO TIO BOJUMU NI ETO ILERA ALABODE WA NIPINLE OYO-NMA LOSOBE.
 • GOMINA IPINLE OYO MAKINDE RO ARINRIN AJO SAUDI LATI GBADURA FUN ILU OYO ATI NIGERIA.
 • AMAJU PINNICK SOPE WON JAWE GBEL EE FUN OHUN SAA OHUN LOPARI NINU AJO CAF.

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background