KOKO INU IWE IROYIN FUN OJO KOKANLA OSU KEWA EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019) OLOOTU: KEHINDE JIMOH

Written by on October 11, 2019

 • JONATHAN KAN SI BUHARI LASO-ROCK.
 • A KO KO AWON OMO NIGERIA WALE MO LATI SOUTH-AFRICA.
 • LORI ORO BOOSI WON FE PASE MIMU AMBODE.
 • BILIONU META O LE DIE NAIRA NI BUHARI ATI OSIBAJO YOO NA LORI IRINAJO WON.
 • OGOJE MILIONU OLE MESAN NAIRA MI ARE ATI IGBAKEJI YOO FI JEUN.
 • O LE LEEDEGBERUN AWON TI KO KUNJU OSUWON GEGE BI 0LUKO NI KWARA TI WON YO LE DANU.
 • AWON ONIBON JI OLORI ILE EKO GBE NI KADUNA.
 • AWON IPINLE KO NI GBA OWO ATUNSE OPOPONA MO-IJOBA APAPO
 • IJOBA IPINLE BENUE RU OLUKO POLY LO SI KOOTU LORI ESUN IFIPABOBIRIN LOPO.
 • IJOBA IPINLE EKO SAYEWO FAWON TO N LO ISREAL.
 • OLOOPA IPINLE DARA JU-GURU MAHARAJI
 • AWON OLUKO POLY FE DASE SILE.
 • ONDO TI AWON ILE-IWOSAN KAN PA.
 • O TI LE NI OGORUN EYAN TI WON JI GBE NI TARABA.
 • OWOYA NI MON WA LO SI ILE OKERE- FAYEMI  

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background