KOKO INU IWE IROYIN FUN OJOETI OJO KEJILA OSU KEJE EGBAA ODUN OLE NI MOKANDINLOGUN (2019 OLOOTU: ADBUL GAFAR ABDUL FATAI

Written by on July 12, 2019

 • IWADI FIHAN PE AWON ASOFIN ILEEYI, AWON OLOPA  ATI AWON ADAJO NI OLORI AWON OJELU NILEEYI.
 • AWON MEKUNNU ILEYI TIGBERA LATI MERINDIN LAADORIN MILLIONU SI MEJIDINLOGORUN MILLIONU LAARIN ODUN MEWA.
 • AWUYEWUYE TI POJU LORI ORUKO AWON MINISITA TIMOFEKO BUHARI KIBOSI.
 • AWON TIMO MO IWA WON DENUDENU NI MAAYAN SIPO MINISTA ARE BUHARI LOWIIBE.
 • AWON EBI ADELEKE SOPE AWON KOGBA KI ADELEKE TUN GBA TIKETI GOMINA MO LODUN 2022 NIPINLE OSUN.
 • EEFIN GENERATOR PA TOKOTAYA ATI OMO MARUN NIPINLE RIVERS.
 • NIBI IJAMBA INA OSISE PANAPANA MEJI KU ENIYAN MEJIDINLOGOTA TELE WON NIPINLE BENUE.
 • IJOBA IPINLE EKO GBESELE PONMO OLORO ASEKUPANI NILU IJEGUN ATI IKOTUN.
 • JONATHAN KESI IJOBA APAPO LATI SE AMULO ESI ABAJADE IJOKO APERO GBOGBO GEGE BI ONA ABAYO SII ABO ATI ORO AJE.
 • AWON OMO EGBE SHITTE FEHONU HAN LORI AIYONDA ASAAJU WON.
 • SUPER EAGLES YIO WOYAAJA PELU ALGERIA NI OJO SUNDAY FUN IPELE SEMI-FINAL NIBI IDIJE ILE ADULAWO TONLO LOWO LORILEEDE EGYPT.

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background