- Awon agbebon pa Eeyan meji, won ti ji
alufa ijo Aguda gbe ni Kano,Benue .
- Eni meji ti won furasi nipa Corona virus
nilu Eko yege leyin ayewo ilera won, ko si aisan naa lara won.
- Ileegbimo asoju beerefun alekun ipese
owo fun amojuto corona virus .
- Ajo SERAP ro gomina Sanwolu lati bowo
fofin ileejo to tako kawon ileewosan iJoba maa gbe eje loranyan, ki won to bere
toju.
- Dokita oyinbo kan nile yi nilati setoju
alaisan to din die legberun meja, Ijoba apapo kede abajade iwaji.
- Ajo alakaso agbegbe Niger Delta leri
lati fopinse gbigbe ise akanse sita lona to mehe.
- Ijoba ipinle Rivers fi igbaradi han lati
koju corona virus.
Reader's opinions