KOKO INU IWE IROYIN FUN OJORU OJOKEDOGUN OSU KINNI ODUN EGBA O-LE-OGUN (2020) OLOOTU: MORUF ADEDEJI

Written by on January 15, 2020

  • AWON ESO KANPA-TASK FORCE TI PRESIDENT OFFICE LABE IGBAKEJI ALAGA KAYODE OPE-IFA TI KE GBAJARI SITA LORI AWON TIO NI DUKIA LEGBE OMI FI YI AGBEGBE WON SI BI AWON OKO AFAYAFA PELU GORODOMU LORI N GBE AWON OKO WON SI
  • IJOBA IPINLE OYO LABE GOVERNOR SEYI MAKINDE TI YA MILLIONU MERINLE LADORIN (54) SOTO FUN ETO ILERA.
  • IJOBA APAPO TI NI AFARA SI GBE ALABO AMOTEKUN NIN AWON IPINLE YORUBA KO BA OHUN MU.
  • AWON GOMINA SOUTH-WEST TI NI AWON SETAN LATI GBE IGBESE LORI BI IJOBA APAPO SETAKO OPERATION AMOTEKUN
  • AWON AJO OLUKO-FASITI ILE WANI FAOD LERAN LORI IPPIS , EYI TI WORO PEPE FUNU ETO EKO TI O FARARO NIPINLE.
  • ILEEJE TOI OGAJULO SUPREME COURT TI KEDE PE SENATOR HOPE UZODINMA (APC)  LO JAWE OLUBORI GEGE BI GOMINA ADIBOYAN NIPINLE IMO KI EMEKA IHEDIOHA KURO LORI AG-ADAJO KUDIRAT KEKEREEKUN LODAJUMA LANA ODEYI


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background