OMO ILE CHINA TI WON SAYEWO RE NILEEWOSAN NILU EKO BOYA O NI AISAN CORONA VIRUS, ABO IWADI FIHANPE KO NI ALEEBU ILERA KANKAN

Written by on February 27, 2020

Ijoba Ipinle Eko sope, omo Ile China ti won mulo sileewosan Reddinghton nilu Ikeja latari pe won furasi pe o ni aisan Corona Virus , ni iwadi awon onisegun oyinbo pada fidere mule pe saka lara re da o.

Komisona Eto Ilera, Ojogbon Akin Abayomi lo soro naa ninu atejade to fi sita woye pe, ko si apeere pe omo Ile Chins nss ni kokoro aisan Corona Virus lago ara, eleyi to jeko won fenuko pe i tu sakosile aisan corona virus koakan pato nipinle Eko di asikoyi.

Nigbai to nse atupale abo iwadi naa, Ojogbon Abayomi salaye pe logan tiroyin te ajo eleto Ilera Ipinle Eko leti nipa eni won farasi pe o ni aisan corona virus nileewonsan Redington lawon to tanroran.

O wa ro awon olugbe lati maa se gbe iroyin eleje kiri nipa aisan lojuna ati maa baa ko iberubojo baraalu, o ni iroyin to ti afiisi ajo eleto ilera jade nikan lo je ogidi.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background