ÀDÉLÉBÁRE
Bond FM
Scheduled on
Monday | 4:30 pm | 8:00 pm | |
---|---|---|---|
Tuesday | 4:30 pm | 8:00 pm | |
Wednesday | 4:30 am | 8:00 pm | |
Thursday | 4:30 pm | 8:00 pm |
Àdélébáre
Tagged as:

Ẹ darapọ̀ mọ́ wa ní gbogbo ọjọ́ lórí ètòo wa “Àdélébáre”, ètò tí a gbé kalẹ̀ fún àwọn arìnnà ti ó ń lo sílé láti ibi iṣẹ́ òòjọ́ọ wọn. Agogo mẹ́rin àbọ̀ ní àárín ọ̀sẹ̀ (Ọjọ́ Ajé sí ọjọ́ Ẹtì).
A ò ní rìn lọ́jọ́ tí ebí bá ń pa ọ̀nà. Àdélébáre, arìnnà kore, àkòyàibi!!!
Read more