ÀLÀYÉ BÀBÁ Ọ̀RỌ̀
Bond FM
Scheduled on
Thursday | 9:30 am | 10:00 am |
---|
Tagged as:

Là á hàn mí ni bàtá nh ké l’Ótù Ifẹ̀, lórí ètòo Àlàyé Bàbá Ọ̀rò ni a ti ń tú kókó ti ó wà nínú èdèe Yorùbá. Bí o bá tó gbangba á sùn lọ́yẹ́, o lè dáhùn ìbéèrè. Pàdée Túnjí Ọlálékan ni ọjọọjọ́ọ Ọjọ́bọ̀ ní agogo mẹ́sàn-án òwúrọ̀ (9:30 - 10:00 òwúrọ̀).
Read more