KÓKÓ INÚ ÌWÉ ÌRÒYÌN
Bond FM
Scheduled on
Monday | 6:00 am | 9:00 am | |
---|---|---|---|
Tuesday | 6:00 am | 9:00 am | |
Wednesday | 6:00 am | 9:00 am | |
Thursday | 6:00 am | 9:00 am | |
Friday | 6:00 am | 9:00 am | |
Saturday | 6:00 am | 9:00 am | |
Sunday | 6:00 am | 9:00 am |
Kókó Inú Ìwé Ìròyìn
Tagged as:
Ojoojúmọ́ ni pátákó alápatà ń gba ọgbẹ́, ojoojúmọ́ ni Kókó Inú Ìwé Ìròyìn-in Bond 929FM ní 6:15 òwúrọ̀ – 9:30 òwúrọ̀. Ní orí ètòo Kókó Inú Ìwé Ìròyìn ni a ti ń yọ àwọn kókó tí ó wà nínú ìwé ìròyìn kà sí etí ìgbọ́ọ yín. Kókó Inú Ìwé Ìròyìn ń tèsíwájú!!!

Read more