#Court

Egbe awako oko afayafa nile Nigeria ti rawo ebe si ijoba apapo lati pase fawon agba isese to nsise ojuko marose Oshodi-Apapa ati Tincan si Mile 2 ki idamu to won nkoba awon awako oko afayafa dinku jojo.

Ijoba ipinle Eko ti rawo ebe sawon ero ti nlo ojuupopo lati se suru fun ijoba toripe won o feki ojo sakoba fawon ise akanse lo jeki won dawole opolopo ise akanse papo lasiko kan naa.

EGBE ASUU ATAWON MIRAN FAJURO SI SISUN AYEYE ASEKAGBA AWON AKEKO UNILAG SIWAJU
OKO AFAYAFA SEKUPA MOLEBI ELENI MARUN LORI OKADA NI KANO

Gomina Ipinle Eko, Ogbemi Babajide Sanwo=Olu ti fajuro sowon gogo ti won nta omi ifowo aoakokoro ati ibomu latari bi ero se nro ketiketi lo ra loja nitori aisan coronavirus to seleru nilu Eko latowo omo Italy to ko aisan naa wa silu Eko, ti won si fo sahamo sisamojuto ilera re leaye oto.

Pelu bawon Kristen lagbaye se asajoyo ayajo Ojoru Eeru lori ode yin, won ti fun omo Nigeria papajulo awon kristen nimoran lati sunmo Olorun ninu adura , ise ore ati emi arojinle.

ILE EJO DA EWON ODUN MEJE FUN OLISA METUH ALUKORO PDP TELERI
IJOBA APAPO PE AWON AMUGBALEGBE OSINBAJO TI WON YO NISE PADA

Aya Gomina ti Ipinle Eko, Dokita Ibijoke Sanwo-Olu ti se ileri lati tesiwaju ati maa se iranlowo fun awon alaini ni Ipinle Eko papajulo, awon ti ijamba ina sele si ni Agbegbe Abule-Egba ni ibere Osu kinni Odun yi ti won si ko won lo si LASEMA IDO Camp, ni Igando.

YOO PADA RE IJA LORI BIJOBA SE TE ENU IBODE PA, EGBE MAN LO SO BE
AWON AGBEBON PA OSISE OGA AGBA KAN NI ASO ROCK, WON DANA SUN OKU RE

Awon gomina gomina ni ile Yoruba tise alaye pe kun sepe awon se idasile eso alaabo iwo orun ti won tinse amotekun bikinse lati daabobo ileto ati ekun ile Yoruba lo.

IKOLU-KOGBA NIPINLLE BAYELSA NI GBATI SUPREME COURT NI APARO FUN DEBENI DAVID-LYDN NINU EGBA APC PEDUN OGBODO EGBE ASEFUN


Current track

Title

Artist

Background