WON TI FUN AWON AKEKO ILEEWE IJOBA NIPINLE EKO LARIDAJU ORO PE AABO EMI ATI DUKIA WON KI BEWU DE

Written by on November 6, 2019

Ijoba Ipinle Eko fi okan awon akeko ileewe ijoba ipinle Eko bale pe aabo gidi wa fun emi ati dukia won.

Gomina Babajide sanwo-Olu soro naa nibi eto ilaniloye to waye fawon akeko nifasiti, LASU pelu titunmo idi tawon akeko fi gbodo takele sown iwa ibaje kojoola won le dara.

Gomina ti omoba adeyemi adebowale lo sojufun fajuro si bawon akeko kan se maa nkegbe kegbe tabi darapo mogbe okunkun, eleyi to je ki kosi awon obi atalagba to lati marasitoju omo won daada.

Ninu oro igbakeji giwa Fasiti LASU, ojogbon Olumuyiwa Noah, lo ti soye oju merin lo nbimo, igba oju lonwo.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background