WON TI RO AWON OMO NIGERIA LATI FOPIN SI IWA ITABUKU AWON OMOBINRIN
Written by Christiana Akano on October 11, 2019
Gbogbo iyanju ni a gbodo gba lati se aforo fun awon iwa itabuku awon omo-obinrin leyi to n te eto won loju nile yi.
Ninu atejade kan, lati owo oludari Agba kan nile yi Ogbeni Akin Jimoh lati fi sami ayeye awon omo obinrin lagbaye toka si i pe awon omo-obinrin ileyi gbodo ji riro lagbara nipa Eto Owona, Eto eko, Ise-Owo to ye kooro tori pe awon omo-obinrin niiya n je ju to ba doro ifabukun kan ni.
Ogbeni Jimoh so po ayipada diedie ti n wa lori awon ise ironilagbara awon omo-obinrin sugbon orile eede yi gbodo gbiyanju si i.
Gbogbo ojo kokanla osu kewa odun ni Ajo Isokan agbaye ya soto fun ayajo awon omo-obinrin.