ÀLÁÁFÍÀ TÁYỌ̀
Bond FM
Scheduled on
Wednesday | 11:00 am | 11:15 am |
---|
Àlááfíà Táyọ̀
Tagged as:
Àwọn àgbá bọ̀, wọ́n ní ìlera ni oògùn ọrọ̀, bákan náà ni wọ́n ní àlááfíà táyọ̀, èyí ni a fi gbé ètòo Àlááfíà Táyọ̀ kalẹ̀ fún gbogbo àwọn tí illera ara wọ́n bá jẹ lógún. Lórí ètò yìí ni a ti máa ń sọ ohun tih ó jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ìlera. Ẹ darapọ̀ mọ́ wa ní ọjọ́ọ Ọjọ́rú (Wednesday) ni déédéé agogo mọ́kànlá òwúrọ̀ 11:00.
Read more