AMI EYE FUN STEPHEN BANJI-AKINTOYE

Written by on November 6, 2019

Omo Nigeria ni ojuse lati sowopo pelawon oloselu wa lojuna ati lulo mayederun faraalu.

Alenuloro omo Yoruba atata kan, Ojogbon Stephen Banji Akintola lo soro ipenija naa lasiko to gbalejo awon asoju egbe Yoruba Indigenes Foundation, YIF, nile re towani Magodo, lEko.

ojogbon Akintoye ro egbe naa lati tubo duro wamuwamu, kawon ile to ile Yoruba le yan ninu ise idagbasoke ilu ijoba gunle.

Ninu oro tire, Aare egbe YIF, comrade Olumide Aderinbole, lo ti sope abewo naa soodosiwon lati wa gbamoran ni.

Nibi abewo naa won ti kede ami eye fun Ojogbon Stephen Banji-Akintoye gegebi baba egbe won.


Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background