KOKO INU IWE IROYIN FUN OJOISEGUN OJO KEJI LELOGUN OSU KINNI ODUN EGBA-O-LE OGUN OLOOTU: FUNSHO ADEOLU

Written by on January 21, 2020

  • ILE EJO TO GA JULO BUWOLU IDIBO SIPO GOMINA GANDUJE, LALONG, TAMBUWA ATI MOHAMMED
  • OLU ILE-ISE OLOGUN ILEYI RO AJO ORILE EDE ILU OYINBO LATI FOPIN SI ATILEHIN AWON EESIN O KOKU
  • GOMINA BAYELSA, DICKSON SOWIPE AMOTEKUN TI KUKU WA PE FUN ATUNTO ORILE-EDE YI
  • GOWON ATI ABDUL SALAMI SALO IYAN LODUN 2050
  • OLORI ADAJO NLEYI, MALAMI KOWE SI GOMINA MAKINDE TI OYO LATI DA AWON ALAGA COUNCIL TO YO PADA SIPO
  • AJO ESO ALAAGBO LOJU POPO NGBERO ATI SE IWE IRINNA ATIWAKO FUN LILO LOKE OKUN
  • LATARI INA EPO TO SELE LEKO, EYAN MARUN LO RORUN OPO DUKIA LO JONA
  • AARU KOOLI YIRUN YIRUN PA EYAN MEEDOGUN
  • ARAKUN KAN LU IYAWA RE PA NI IPINLE OGUN
  • ISE OJU IRIN EKO SI IBADAN KO LE PARI LOSU KERIN
  • ORO AMOTEKUN KO NIISE PELU PELU ESIN KAN O-AKEREDOLU
  • EYAN METADILOGUN KU, MERINLA FARADA NINU IJAMBA OKO OJUNA KASTINA
Tagged as

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *



Current track

Title

Artist

Background