KOKO INU IWE IROYIN FUN OJO KERINDILOGUN OSU KINNI EGBA ODUN O-LE-OGUN (YEAR2020) OLOOTU: TUNJI OLALEKAN

Written by on January 16, 2020

  • AWON AGBAAGBA ILE YORUBA ATI AWON AGBEJORO AGBA BU ENU ATE LU MALAMI LORI OHUN TI O SO NIPA AMOTEKUN
  • AJO ELETO ILERA AGBAYE W.H.O TAARI IPENIJA TI YOO JEYO JADE FUN ODUN MEWAA TI O MBO
  • AARE BUHARI, AWON OLORI ETO AABO LORILE EDEYI ATI AWON GOMINA BU OLA FUN AWON OMO OGUN TIO SUBU LOJU IJA
  • AWON GOMINA SELERI OPO IRANWO SII FUN AWON OLOGUN ATI AWON MOLEBI AWON OMO OGUN TI O SUBU LOJU IJA
  • AJO ELETO IDIBO FUN UZODINMA NI IWE ERI BIBO SI IPO GOMINA NI IPINLE IMO
  • GOMINA SANWO-OLU RAWO EBE SAWON OMO NAIJIRIA LATI JE KI ALAAFIA ATI ISOKAN JE MIMU LOKUNKUNDUN
  • IJOBA IPINLE OYO TI BI AWON AKEKOO BA SE SE SI NI AWON OLUKO WON YOO SE MAA NI IGBEGA LENU ISE SI
  • IYA KAN TI O BI OMO MEJI GBEMI ARA RE NIPINLE OSUN NITORI PE O JE GBESE                                                 

Reader's opinions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *Current track

Title

Artist

Background